Compulsory Course

Ha! ha!! Kaka lo tobi to bayi Ibebe lo tobi to bayi ha! Kaka lo tobi to bayi Ibebe lo buru to bayi Kaka lo tobi to bayi Compulsory course ni ise yi Mathematics ma teti le o ise yin Wa love me to ba je idi ni mathematics Ibile! Hayi! Thou shall not carry over Any course One unit course Two units course Four units course Ibile! ibile!! wo! Aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!) Mo fe se yin ni anfani E te ti ke ti e gbo offer mi Aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!) Mo fe se yin ni anfani E te ti ke ti e gbo offer mi Hayi! hayi!! wo! Compulsory course ni ise yin Compulsory course ni ise yin Compulsory course ni ise yin Ko olorun ma je n carry ise yin Compulsory course ni ise yin Compulsory course ni ise yin Compulsory course ni ise yin Ko olorun ma je n carry ise yin Ahn! wo! Lalakukulala Iwa buruku ba e dagba Iwo ni vixen Iwo ni dancer Mogbo pe o n jijo You’re so bad like that High like that Kekere lo ti ja by far Ise woli ise alfa Mogbo pe on gbawe adura a gba (ha!) Sister veronica E n je ise laphorita Home and away le tun ta (ha) market yin ta Eje mon lo ko kin se omi Won ni four rounds ko kin yo yin o Won ti cast ladugbo yin o Ibile! ladugbo yin oo Foto foto (foto foto) O para para (e para pare) E dara dara…..bi omi o Hayi! ibile! ibile!! Eje mon lo ko kin se omi Won ni four rounds ko kin yo yin o Won ti cast ladugbo yin o Hayi! ladugbo yin oo Je o mo! Aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!) Mo fe se yin ni anfani E te ti ke ti e gbo offer mi hayi! Aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!) Mo fe se yin ni anfani E te ti ke ti e gbo offer mi Hayi! hayi!! wo! Compulsory course ni ise yin (mathematics) Compulsory course ni ise yin (physics) Compulsory course ni ise yin Ko olorun ma je n carry ise yin Compulsory course ni ise yin Compulsory course ni ise yin Compulsory course ni ise yin Ko olorun ma je n carry ise yin Ha! ha!! Kaka lo tobi to bayi Ibebe lo tobi to bayi ha! Kaka lo tobi to bayi Ibebe lo buru to bayi Kaka lo tobi to bayi Compulsory course ni ise yi Mathematics ma teti le o ise yin Wa love me to ba je idi ni mathematics