Tuesday, December 3, 2024

Naira Marley – Soapy [Music video & Lyrics]

Stream and watch Soapy by Naira Marley [Music video & Lyrics]

 

O t’ẹsẹ’le bọYahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)Ole l’everybodyẸni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo(Barawo, barawo, barawo)(Mọ ba ṣa ni barawo)O tẹsẹ’le bọ (O tẹsẹ’le bọ)Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)Ole l’everybodyẸni ilẹ mọ ba ṣa ni barawoO fẹ ṣe’ka fun mi (O fẹ ṣe’ka fun mi)Mi o l’ogun mo ni Kurani (mo ni Kurani)Mo dẹ n ṣ’adura miBi m ṣe n ṣ’adura miAllah n gba’dura mi (Allah n gba’dura mi)A ti lọ a ti de (A ti lọ a ti de)Ẹni ori yọ o di’le (Ẹni ori yọ o di’le)Ẹni ba lọ l’o ba deIgba ti m pada deN’ṣe l’ọn de mi l’ade (N’ṣe l’ọn de mi l’ade)K’ade ko pẹ l’ori (K’ade ko pẹ l’ori)Ki bata k’o pe l’ẹsẹ (Ki bata k’o pe l’ẹsẹ)K’awọn ọta mi kan l’ẹsẹInside life (Inside)O ti ri 5 Alive (O ti ri 5 Alive)Inside life (Inside)O ti ri Deeper Life (O ti ri Deeper Life)Inside lifeAwọn kan n jẹ’yaAwọn kan n chop life(Inside life) Inside lifeAwọn kan n ṣ’epeAwọn kan n jẹ’waJo soapy, soapyKirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)Jo soapy, soapyIkoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)Jo soapyNinu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)Jo soapyT’o o ba ni’yawo n’le k’o jo soapy(Soapy!) soapy, soapyBọda yi n jo soapy (Bọda yi n jo soapy)Soapy (Soapy)Ab’ẹyin naa soapy? (Ab’ẹyin naa soapy?)Soapy (Soapy)Single father n jo soapy (Single father n jo soapy)Soapy, ma lọ lo OMO t’o ba lọ n soapy (Soapy!)Ṣ’o d’owo mọ? (Ṣ’o d’owo mọ?)O wa sọ p’o o mọ Naira (O wa sọ p’o o mọ Naira)O wuwo l’ọwọIwọ ṣaa ṣẹ si Naira (Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira)Aja fẹ de’na d’ẹkunKekere ẹkun o ma n s’ẹgbẹ aja (ko n ṣ’ẹgbẹ aja)Wọn n bẹ ni, Ma fọAwọn naa o fẹ wahala (Awọn naa o fẹ wahala)I just wanna make Mama proud (I just wanna make Mama proud)They want to make Mama cryMama you gonna cry no moreT’ẹ ba sun’kun gan ẹ o sọ’kun ayọ (ẹ o sọ’kun ayọ)Ti m ba n jo k’ẹ ba m yọ (k’ẹ ba m yọ)K’ọrọ mi ja s’ayọ (K’ọrọ mi ja s’ayọ)Inside life, Inside lifeDo a one course, it’s my life (Ku’onbẹ!)Inside life (Inside)O ti ri 5 Alive (O ti ri 5 Alive)Inside life (Inside)O ti ri Deeper Life (O ti ri Deeper Life)Inside lifeAwọn kan n jẹ’yaAwọn kan n chop life(Inside life) Inside lifeAwọn kan n ṣ’epeAwọn kan n jẹ’waJo soapy, soapyKirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)Jo soapy, soapyIkoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)Jo soapyNinu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)Jo soapyT’o o ba ni’yawo n’le k’o jo soapy(Soapy!) soapy, soapyBọda yi n jo soapy (Bọda yi n jo soapy)Soapy (Soapy)Ab’ẹyin naa soapy? (Ab’ẹyin naa soapy?)Soapy (Soapy)Single father n jo soapy (Single father n jo soapy)Soapy, ma lọ lo OMO t’o ba lọ n soapy(Soapy!)

Related Articles

Hot this week

Davido and Chioma to shut down US for twins’ 1 year birthday

Davido and his wife, Chioma, are reportedly planning to...

Does Bras Actually Prevent The Breasts From Sagging And Falling?

Many women struggle with the insecurity of sagging breasts...

Single ladies weep as Mercy Eke’s shows off surprise gift from her mystery man

Mercy Eke, the former Big Brother Naija winner, shared...

Senator Mustapha encourages FG to make Agriculture Studies compulsory

Senator Saliu Mustapha highlights the importance of Agriculture and...

Very dark man Biography: Age, Family, Education and Career

Martins Vincent otse, better known as very dark man,...