Saturday, January 18, 2025

Asake – 2:30 (Music video & Lyrics)

Àwa dé, àwa dé-déÀwa l’ọmọ tọ ń sọ, ti o seke, yeOrímọlade gbe mi de’bẹJigan, jigan, ẹsẹ mi o de’lẹ, de’lẹÀlàyé mi, stop ṣe bẹO fẹ jẹ ń bi, o tún fẹ jẹ ń bẹ, ò pọ, sẹAgba-awo, f’ẹnu fo fence, sún s’ẹhìnÀmọ ‘rawa, ṣ’o get?
Abínibí yàtọ sí abilityẸ sọ̀ fún wọn t’oba tẹ’ri si, wọn má pa l’óríT’ẹnu kọ, emi promisingAwọn tẹ fọ fun, fọ fun miTorí ko s’ẹlòmíì, many men fẹ dàbí mí, ẹ ri biẸ gbé Ọlọrun tóbiMo d’aṣọ ẹbi for my countryYou can call me Mr. Money
Mm-mm-mm, mm-mm2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki’lẹ to mọMm-mm-mm, mm-mm (ye-ye, ye)2:30 fẹ lu (2:30 fẹ lu), oya, ka turn up, ki’lẹ to mọ
Èrè mò bawa, ko si ijaṢòkòtò penpen, ye, àyé ni’kaYebo, yebaFormulation lo gba, yejaỌmọ iyami, ko stay wiseTranquillity, tranquillityI no get time to dey form activityKo le kalas, I dey find stability
Like Abacha, money long, infinityWhat’s the chances, what’s the probabilityTo see a better version of me with agility?No, you can’t fake realityOgun principalities and calamityMo ti lọ, mo ti pá ‘yẹn tiBẹbẹ no dey for Jiji, o ṣí wa ń títíStill get money like FitiDrippin’ like Fiji, I be real G
Mm-mm-mm, mm-mm2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki’lẹ to mọMm-mm-mm, mm-mm2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki’lẹ to mọ

Related Articles

Hot this week

Ayo Maff Biography: Age, Family, Education and Career

Ayomide Mafoluku Ayodele, better known as Ayo Maff, was...

Paul Tomisin Biography: Age, Family, Education and Career

Minister Paul Tomisin is a celebrated gospel artist known...

Very dark man Biography: Age, Family, Education and Career

Martins Vincent otse, better known as very dark man,...

Does Bras Actually Prevent The Breasts From Sagging And Falling?

Many women struggle with the insecurity of sagging breasts...

Davido and Chioma to shut down US for twins’ 1 year birthday

Davido and his wife, Chioma, are reportedly planning to...